Akomolasha Group

  • Home
  • Akomolasha Group

Akomolasha Group Actor & Actress Group

23/04/2021

Call Mc-Akomolasha for any party's or WhatsApp me on this number 09022014102

16/07/2019

My Chinese wife is 8months pregnant.........Help me with Chinese names.

12/11/2018

I Love You All

03/07/2018

AKOLE ITAN YI NI"ODOLANGBA''E MA BA MI KALO(olori Amope:-kabiesi O,kade O Pe Lori Ki Bata O Pelese,Oro Kan Lo Nja Ninu Mi Lati Bi Ojo Melokan Seyin Ti Mo Fe Bayin Ji Roro Le Lori.(Oba:-Oro Kii Tobi Kafobe Buu,lahan Mi Ni Bata Nke,so Fun Mi Kin Gbo.(olori Amope:-Oro Lori Omo Kan Soso Ti Oba Oke Fifun Wa Yii Naa Ni.Kabiesi Iba Dara Kafi Oladapo Omo Wa Si Ile Eko Nitori Ojo Iwaju,yoo Je Ohun Iyi Fun Wa,lojo Waju,paapaa Julo Laarin Awon Ijoye,bi Eyin Naa Se Mo,omo Eni Ni Selede Leyin Eni,kabiesi Ohun Iwuri Ni Yoo Je Pe,ori Yin Ni Omowe,gbajumo Oba Yio Ti Bere.(Oba:-Olori,o Kuu Laakaye Oye Ti Oba Oke Fifun O Koni Baje,oro Bi Oyin Bi Adun,o Nbe Ninu Re Lati Bi Ojo Melokan,o Wi Jade,aya Mi,abi Eru Mi Ba O Ni? Maa Beru Tori Mo Fe O Tokantokan,mo Fe O Ju Gbogbo Awon Olori Kekere,ti Won Fi Agidi Fun Mi Nigbati Mo De Ori Te Baba Mi,olori;oro Pataki Loo Bami So,eyi Koni Je Ki Oruko Mi O Pare Nile Baba Mi Lailai,ni Bayi_bayi Mo Ti Bere Sini Se Eto Bi Oladapo Yoo Se Bere Ile Eko.(AO NI RI JU BAYI LO,IPADE TUN DOLA OOO)

22/05/2018

God Is In Control

15/05/2018

Address

Awotan Koiditan Road 1 Apete Ibadan

Telephone

09024493991

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Akomolasha Group posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

  • Want your club to be the top-listed Nightclub?

Share